Ìgbìmọ̀ aláṣẹ Nàìjíríà gbóríyìn fún Mínísítà fún Iṣẹ́ -ọ̀gbìn tí ó dolóògbé
Àwọn ọmọ ìgbìmọ̀ aláṣẹ ní ọjọ́ọ́rú, gbóríyìn fún mínísítà fún iṣé-ọ̀gbìn ní orílẹ̀-èdè nígbàkan rí,tí ó dolóògbé ní ọjọ́ Àìkú.
Akowe fun Ijọba apapọ, Ọgbẹni Boss Mustapha kede iku Malami Buwai,tii ṣe ẹni…