Ìdùnnú ṣubú layọ̀ Teebillz
Ọlọ́run ti fi ọmọkùnrin tuntun ta Ìkan lára àwọn olùṣàkóso ẹ̀bùn ní Nàìjíríà, Tunji Balogun tí a tún mọ̀ sí Teebillz, lọ́rẹ pẹ̀lú ọ̀rẹ́bìnrin rẹ̀.
Oludari orin naa pin fọto ati fidio ọmọ rẹ, Zayn lori Instagram.…