Ìdìbò gómìnà Kogi : “A ní olùdíje tó dára, ẹ yẹra fún ìwà ipá” – Ǵomìnà Bello
Gómìnà ìpínlẹ̀ Kogi, Yahaya Bello ti gba àwọn olólùfẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress (APC), nímọ̀ràn láti yẹra fún ìwà ipá, nítorí pé ẹgbẹ́ náà ní olùdíje tó dára, tí ó jẹ́ Usman Ododo fún Ìdìbò…