Ìdìbò: Ààrẹ Bùhárí gúnlẹ̀ sí ìpínlẹ̀ Katsina
Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárì ti gúnlẹ̀ sí ìpínlẹ̀ Katsina láti dìbò gómìnà àti ti ilé ìgbìmọ̀ aṣojú ṣòfin ìpínlẹ̀ ,ọdún 2023.
Ààrẹ gúnlẹ̀ ní dédé agogo mẹ́ta kọjá ogún ìṣẹ́jú ìrọ̀lẹ́,sí pápá òfurufu…