Ìdìbò 2023: Ẹ dín owó Fọ́mùù ìdíje yàn fún Àwọn asojú- ọ̀dọ́
v
Aṣojú àriwá Kwara níbi Àpèjọ Karùn ùn Àwọn ọ̀dọ́ Nàìjíríà, Ibraheem Abdullateef, képe àwọn ẹgbẹ́ òsèlú pàtàkì láti dín owó fọ́mùù yíyan olùdíje kù ṣaájú ìdìbò 2023, láti fààyè gba ìjọba…