Hajj 2023: Àjọ Élétó Hajj Gbé Ẹgbẹ̀rún Ogójì Lé Díẹ̀ Àwọn Àrìnrìn-àjò Pàdà Sí Nàìjíríà Láàrín Ọ̀sẹ̀…
Láàrín ọ̀sẹ̀ méjì tí Àjọ élétó Hajj tí Nàìjíríà "National Hajj Commission of Nigeria (NAHCON)" bẹ̀rẹ̀ sí kó àwọn àrìnrìn-àjò náà wọlé, ó tí gbé ẹgbẹ̀rún lọ́nà ogójì lé díẹ̀ (42,256) nínú àwọn àrìnrìn-àjò ẹgbẹ̀rún àádọ́rin lé mẹ́ta 73,000…