Gómìnà Cross River Dá Àwọn Ọmọ Nàìjíríà Mẹ́wàá Lọlá
Gómìnà ìpínlẹ̀ Cross River tó wà ní gúúsù Nàìjíríà, Bassey Otu tí ṣé ayẹyẹ ayajọ nlá kán fún àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà mẹwàá fún iṣẹ́ ìránsẹ́ wọ́n fún ìdàgbàsókè orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Ayẹyẹ náà tó wáyé ní Calabar, Olú-ìlú Ìpínlẹ̀ náà…