Gómìnà ìpínlẹ̀ Adamawa búra fún àwọn olùrànlọ́wọ́ pàtàkì mẹ́tàlé-lọ́gọ́rùún
Gómìnà ìpínlẹ̀ Adamawa ti búra fún àwọn olùrànlọ́wọ́ pàtàkì tó lé lọ́gọ́rùún tun tun ní orísiríṣi ipele.
Yiyan yii jẹ ọkan lara ìṣe ni gbogbo igba lati tunbọ fun awọn ohun elo ijọba lagbara lati ṣiṣé wọn boṣetọ ati…