Gómìnà Fintiri tẹnumọ́ ìpinnu láti ṣàtúnṣe ìpínlẹ̀ Adamawa
Gómìnà ìpínlẹ̀ Adamawa, Amadu Fintiri tún ń fìdí ojúṣe ìjọba rẹ̀ múlẹ̀, èyí tí ó jẹ́ àti fa ojú àwọn olùdókòwò mọ́ra, kí ó sì ṣàgbéga ìpínlẹ̀ náà àti ìgbélárugẹ oríṣiríṣi Àṣà tí ó mú ìlú náà…