Ààrẹ Tinubu Pàdà Sí Nàìjíríà Lẹyìn Ìpàdé G20 CwA Ní Germany
Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí pàdà sí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lẹyìn tó tí kópa nínú ìpàdé G20 tí wọ́n pé ní 'Compact with Africa (CwA)' tí Alákóso Ìlú Germany Olaf Scholz gbàlejò rẹ̀.
Ọkọ Òfurufú tí Ààrẹ balẹ̀ ní pápá ọkọ̀ Òfurufú 'Nnamdi…