Spain Lú Sweden, Peregede Sí Aṣé-kágbá Ìfé Àgbáyé Àwọn Obìnrin
Orílẹ̀-èdè Spain dé ìpele aṣé kágbá Ìfé Àgbáyé àwọn Obìnrin "FIFA Women's World Cup" nígbà àkọ́kọ́ rẹ̀ lẹ́yìn tí Olga Carmona gbá bọ́ọ̀lù s'àwon Sweden ní iṣẹju aaya sí ìparí 2-1ni ọjọ́ Ìṣẹgun, ní pápá iṣere Eden Park ní Auckland, New…