Àwọn Ẹgbẹ́ Alhamadiyya Pé Fún Àlàáfíà Ní Gaza
Jama'at Mùsùlùmí Ahmadiyya ní Nàìjíríà, tí pé fún àlàáfíà àtí ìdádúró ogún ní Gaza.
Ẹgbẹẹgbẹrun ènìyàn pẹ̀lú àwọn Obìnrin àtí àwọn ọmọdé tí kú nínú ìjà láàrin àwọn ológun Ísráẹ́lì àti Hamas ní Oṣù díẹ̀ sẹ́yìn.
Amir tí Jama'at…