Ẹgbẹ́ Tiv pè fún àlàáfíà láàrin àwọn àgbààgbà tó níkùn sínú síra wọn ní…
Ẹgbẹ́ ìdàgbàsókè Tiv (TIDA), tó wà lábẹ́ àbojútó àwọn ọmọ bíbí inú Tiv ti ìpínlẹ̀ Nasarawa, ti rọ àwọn ọmọ olókìkí méjì rẹ̀, Aṣòfin Boniface Ifer àti Asọ̀fin Peter Ahemba, láti yanjú aáwọ̀ tó wà láàrin wọn…