Ẹgbẹ́ pè fún aṣòfin obìnrin láti rọ́pò Gbajabiamila
Ẹgbẹ́ alájọṣepọ̀ kan, Àwọn obìnrin tí ń gbóbìnrin nígbùnwọ́ dókè, ti rọ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives (APC), ikọ̀ ìpínlẹ̀ Eko, ń gbèrò láti fi aṣojú obìnrin rọ́pò Fẹmi Gbajabiamila ní ilé ìgbìmọ̀ aṣojú.
Ààrẹ…