Lagos City Marathon 2023: Eléré ìje Ọmọ Orílẹ̀-èdè Kenya Bórí Ìdíje Èrè
Edwin Kibet Koech tí orílẹ̀-èdè Kenya tí jáwé olubori nínù ìdíje tí Access Bank Lagos City Marathon ẹlẹẹkẹjọ irú rẹ̀ tó wáyé ní Lagos, Nigeria.
Ìdíje Ere-ije 42km náà bẹ̀rẹ̀ ní pápá ìṣéré orílẹ̀-èdè ní Surulere o sí parí sí Eko Atlantic…