Niger Coup: Aṣojú ECOWAS Ṣé Ìpàdé Pẹ̀lú Ààrẹ Mohamed Bazoum Tí Àwọn Ológun Yọ́
Aṣojú ECOWAS àtí Alákóso Iṣé ìjọba túntún ní Chad, Mahamat Déby Itno tí pàdé pẹ̀lú Ààrẹ Niger Republic, Mohamed Bazoum, ní Olú-ìlú Niger, Niamey.
O jẹ́ ìgbà àkọ́kọ́ tí Ààrẹ náà ní anfààní látí gbàléjò lẹyìn ìgbà tí àwọn ológun yí tí…