Ààrẹ Tinubu Sọ́ Ìdí Fún Ilè-kókó Ètò Ọ̀rọ̀-ajé
Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Bola Ahmed Tinubu tí sọ pé àwọn ìpinnu ètò ọrọ̀-ajé lílé tí ìjọba rẹ̀ gbé, yóò jẹ́ ànfààní fún ètò ọrọ̀-ajé Nàìjíríà láìpẹ́ yìí.
Nígbà tó n sọ̀rọ̀ níbi àpéjọ àwọn oníròyìn kọkandinlogun '19th All Nigerian…