Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ebonyi Yóò Ṣètò Àwọn Ilé-ìwé Ìdàgbàsókè
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ebonyi Ọ̀gbẹ́ni Francis Ogbonna Nwifuru nínú ìgbìyànjú rẹ̀ látí ríi dájú pé gbogbo ọmọ Ìpínlẹ̀ náà ní iṣẹ́ lọ́wọ́, yálà, pẹ̀lú Ilé-iṣẹ́ kàn tàbí àdáni. Ó ṣàfihàn àwọn ètò láti ṣé ìdásílẹ̀ àwọn ilé-iṣẹ́ ìdàgbàsókè mẹ́ta ní…