Àyá Ààrẹ Orílẹ̀-èdè America Ṣé Àbẹwò Sí Nàmíbíà
Àyà Ààrẹ Orílẹ̀-èdè America, Ìyàáfín Dr Jill Biden ló ọjọ́ Kejì ní Namibia bí ó ṣé ṣàbẹwò sí Àjọ Hope Initiative Southern Africa.
Ó jẹ́ àjọ kan tí kì í ṣe ti ìjọba tí ń ṣiṣẹ́ láti fòpin sí òṣì àti ebi ní àwọn àgbègbè tí a yà sọ́tọ̀ ní…