Meg Lanning: Balógun Ìkọ Australia Kó Ní Lè Kópa Nínú Ìdíje Tí Àwọn Obínrin
Balógun Ìkọ Cricket Australia Meg Lanning kó ní lè kópa nínú ìdíje "Women Ashes" bí wọ́n yóò ṣé kojú England, Cricket Australia kéde
Lanning, ẹní ọdún mọkanlelọgbọ̀n 31, ní àwọn onímọ̀ iṣegun òyìnbó tí rọ̀ kó dúró sílé fún itọju .…