Àwọn Ìgbìmọ̀ Kàn Gbóríyìn Fún Orílẹ̀-èdè Niger Fún Ààbò Ìbodé
Ìgbìmọ̀ tí Orílẹ̀-èdè yí fún Àṣà àtí ìṣé tí yìn Orílẹ̀-èdè Republic of Niger fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ológun tó lágbára pẹ̀lú Nàìjíríà látí jẹ́ kí ààbò tó péye wá ní ibodè látí dáàbòbo ìgbésí ayé àti àwọn òun-ìní ní àgbègbè ààlà tí àwọn…