Ìsèdárò : Aarẹ Buhari balẹ̀ sí Yola
Aarẹ Muhammadu Buhari ti balẹ̀ si ilu Yola, ni ipinlẹ Adamawa bayii lati seadro pẹlu awọn ẹbí , ijọba ati awọn eniyan ipinlẹ Adamawa lori ikú oloogbe Ahmed Joda,ti o ku ni ọjọ Ẹti , ọjọ kẹtalaosu kẹjọ ọdun yii.
…