CDS Pé Fún Ìṣọ̀kan Àti Ìwà Réré Àwọn Ọmọ-ogun
Olórí Àwọn Ọmọ-ogun (CDS), Ọ̀gágun Olufemi Oluyede ti rọ àwọn ológun àti àwọn ọmọ-ogun tí Nàìjíríà láti tún ìwà wọn ṣe, kí wọ́n fún ìṣọ̀kan lágbára, kí wọ́n sì dúró ṣinṣin.
Gen. Oluyede sọrọ náà ní àkókò ayẹyẹ àti ìrántí fún àwọn…