Orílẹ̀-èdè Gẹẹsi Ní Orílẹ̀-èdè Àkọkọ́ Látí Pèsè Òun Ìjà Olóró Ọlọna Gigun Fún Orílẹ̀-èdè Ukraine
Orílẹ̀-èdè Gẹ́ẹ̀sì ní Ọjọ́bọ̀ dì orílẹ̀-èdè àkọkọ́ látí bẹ̀rẹ̀ sí pèsè fún Ukraine pẹ̀lú àwọn misaili òun ìjà ọlọna gígùn, èyítí yóò ràn àwọn ọmọ ogún Ukraine lọwọ́ látí kojú àwọn ọmọ ogún Russia.
Ukraine tí n béèrè fún àwọn òun ìjà…