Bá òkú ìṣe ò tán
Àwọn ọmọdé tí ó ní ààrùn jejerẹ ní Sudan tí ń gbé ní ilé ńlá kan tí a npè ní "Ìrétí wà nínú wa" ní olú-ìlú Khartoum, kò sọ̀rètí nù fún ọjọ́ iwájú.
Wọ́n wá láti oríṣiríṣi ìlú ní orílẹ̀-èdè naa ni Ìlà…