Ọwọ́ pálábá àwọn ọ̀daràn sẹ́gi, ẹ wòó bi ikọ̀ ọmọ ogun Nàìjíríà ṣe sewọ́n bí ọsẹ se ń…
Ṣe ọj,ọ́ kan ni tolè ọjọ́ kan ni tolohun, Ikọ ọmọ ogun orilẹ ede Naijiria pẹlu ikọ̀ ọmọ òfúrufú ati awọn agbofinro to wa ni ,ilà oòrùn àríwá (NE), Operation HADIN KAI (OPHK) ti daná sun ọ̀pọ̀lọpọ̀ ikọ ọlọtẹ Boko Haram (BH) àti…