Ikọ̀ ọmọ ogun Naijiria gbógun ti ikọ̀ Boko Haram ní Borno
ikọ̀ ọmọ ogun orilẹ̀ ede Naijiria ti 25, ẹ̀ka HADIN KAI ti Àríwá Ilà –oòrùn, ti daná ogun ti ikọ̀ ọlọ̀tẹ̀ Boko Haram àti àwọn alakatakiti ẹlẹsin musulumi ní ilà oòrùn Áfíríkà nígbá tí wọ́n gbìyànjú láti dojú kọ…