Àwọn akẹkọ̀ọ́ jáde pè fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ìjọba Nàìjíríà lórí ọ̀rọ̀ ẹ̀kọ́
Alága ìgbìmọ̀, Ẹgbẹ́ Àwọn akẹkọ̀ọ́ jáde ti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Igbobi, Bode Thorps ti pè fún àtúnbọ̀ fisọ́kàn nípa ṣíṣe ẹ̀kọ́ lálábọ́ọ́dé fún àwọn ọmọ Nàìjíríà nípasẹ̀ fífọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú Àwọn akẹkọ̀ọ́ jáde ti…