ASUU tẹ̀síwájú pèlú ìyanṣẹ́lódì wọn
Ẹgbẹ́ òṣìṣé olùkọ́ni ti àwọn ìle-ẹ̀kọ́ gíga, ASUU ti fi oṣù mẹ́ta kún ìdaṣẹ́sílẹ̀ rẹ̀ nítorí ohun tí ó ṣe àpèjúwe gẹ́gẹ́ bíi ìkùnà ìjọba láti mú àdéhùn rẹ̀ ṣẹ.
Aarẹ ASUU, Emmanuel Osodeke fi idi rẹ mulẹ ni ọjọ…