Ààrẹ Buhari Ń Ṣé Àtìlẹ́yìn Fún Tinubu
Ààrẹ Muhammadu Buhari ní ọjọ́ Àìkú fí ifiránṣẹ́ kàn ránṣẹ́ sí ilé látí Addis Ababa, Olú-ìlú Ethiopia, níbí tó wà nínú àpéjọ Africa Union AU Summit, ó sọ pé òún mọ́ ìnira tí àwọn aráàlú ń kojú nípa ètò ìjọba lórí owó, "eyi tí yóò mú…