Àmúkúrò Àdínkù: Sẹ́nétọ̀ Ndume rọ NLC láti dá ìyanṣélódì tí wọ́n ń gbaradì fún…
Adarí ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin tẹ́lẹ̀ rí, Sénétọ̀ Mohammed Ali Ndume, ti rọ adarí ẹgbẹ́ àwọn òṣìṣẹ́ Nàìjíríà lápapọ̀ (NLC), láti dá ìyanṣélódì tí wọ́n ń gbaradì fún,tí yóò bẹ̀rẹ̀ ní Ọjọ́ọ́rú dúró. …