Àlúfáà Ìjọ Kátólìkì Rọ Àwọn Adarí Lórí Ìtọrẹ àánú
Àlùfáà ìjọ kan ní ìlú Eko, Wòlíì Adewale Martins ti rọ àwọn ọmọ Nàìjíríà pàápàá jùlọ àwọn adarí ẹ̀sin láti máa ṣe ìtọrẹ àánú fún àwọn ọmọ Nàìjíríà tí wọ́n nílò ìrànlọ́wọ́.
Gẹgẹ bi Alufaa naa ṣe…