Ààrẹ Tinubu Ṣèlérí Láti Dúró Fún Ètò Ọrọ-Àjé Tó Dára Fún Nàìjíríà
Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí ṣèlérí láti ṣé ìtọ́jú ètò ọrọ-àjé Nàìjíríà, èyítí yóò ṣé adínkù nínú owó oúnjẹ, pàápàá júlọ l'àkókò àwẹ Ramadan yìí.
Ààrẹ Tinubu sọ èyí lásìkò tó n sọrọ níbí ìpàdé Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ tí ẹgbẹ́ òṣèlú tí 'All…