Adarí German Olaf Scholz yóò ṣàbẹ̀wò sí Nàìjíríà
Adarí orílẹ̀-èdè German Olaf Scholz, yóò ṣàbẹ̀wò sí Nàìjíríà ní ọjọ́ kọkàndín-lọ́gbọ̀n àti ọgbọ̀njọ́, oṣù kẹwàá 2023.
Ninu atẹjade kan lati ile-iṣẹ ti n ṣoju German ni Naijiria, idi abẹwo naa si ni lati tunbọ fidi…