Aáwọ̀ okòwò: Ààrẹ Bùhárí rán Àwọn Aṣójú Sí orílẹ̀-èdè Ghánà
Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Mùhámmádù Bùhárí ti ṣọ pé kí aṣojú kán lọ sí orílẹ̀-èdè Ghánà láti yanjú aáwọ̀ ọlọ́jọ́ pípẹ́ tó ti wà láàrin àwọn oníṣòwò Nàìjíríà àti ìjọba orílẹ̀-èdè Ghánà.…