Ààrùn Jẹjerẹ: Àjọ rọ àwọn Ààfín láti yẹra fún òòrùn
Ẹgbẹ́ tí kìí ṣe tìjọba kan, Àjọ Ààfín ti rọ àwọn Ààfín láti yẹra fún òòrùn fún ààrùn jẹjẹrẹ àwọ̀. Àjọ náà sọ pé àwọn Ààfín máa ń ní ààrùn jẹjẹrẹ, tí òòrùn sí jẹ́ ewu tó burú jùlọ, tí ó le fa…