Ààrẹ Tinubu ṣèdárò ikú àgbà òṣèlú APC, Cairo Ojougboh
Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu ti daro pẹlu ẹbi Ojougboh, ijọba ati awọn eniyan ipinlẹ Delta State Gusu Naijiria fun iku Dokita Cairo Ojougboh, Adari Alaṣẹ igbimọ idagbasoke Niger Delta (NDDC), nigba kan rí.
Ninu alaye kan ti agbẹnusọ rẹ,…