Ààrẹ Bùhárí ń darí àpèjọ ìgbìmọ̀ aláṣẹ àpapọ̀
Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ń darí ìpàdé Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ àpapọ̀ lórí ayélujára ní gbọ̀ngàn ìgbìmọ̀, ní ọ́fíísì Ààrẹ, Víllà ní ìlú Àbújá.
Awọn ti o wa nibi ipade naa ni Akọwe agba fun Ijọba apapọ,…