Ààrẹ Iran kìlọ̀ fún Ísírẹ́lì pé kó jógun ó mí
Ààrẹ orílẹ̀-èd̀e Iran, Ebrahim Raisi ti kìlọ̀ fún àwọn ológun pé kò ní jẹ́ kí Ísírẹ́lì sinmi tí ó bá gbé ìgbésè tí ó dojúkọ ìjọba olómìnira mùsùlùmí.
Ikilọ naa waye lọjọ aje, bi ologun Iran ṣe ṣafihan awọn…