Ààrẹ Bùhárí ń darí àpèjọ ìgbìmọ̀ aláṣẹ Àpapọ̀
Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ń darí ìgbìmọ̀ aláṣẹ àpapọ̀,èyí tí ó ń wáyé ní gbòngàn ààrẹ,Villa, ní ìlú Àbújá.
Igbákejì ààrẹ, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmí Ọ̀ṣínbàjò, ọ̀gá àgbà fún àwọn òṣìṣẹ́ ààrẹ, Ọ̀jọ̀gbọ́n…