Ààrẹ Bùhárí ń darí àpèjọ ìgbìmọ̀ aláṣẹ
Ààre Mùhámmádù Bùhárí ń darí ìpàdé Ìgbìmọ̀ aláṣẹ lórí ayélujára ní yàrá àpèjọ ti ọ́fíísì Ìyáàfin àkọ́kọ́.
Awọn ti o wa nijoko nibi ipade naa ni, Igbakeji Aarẹ, Yemi Osinbajo, Akowe agba fun Ijọba apapọ,…