Ààrẹ Bùhárí gúnlẹ̀ sí Addis Ababa fún ìfilọ́lẹ̀ Prime Mínisità
Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí gúnlẹ̀ sí orílẹ̀-èdè Addis Ababa, olú-ìlú Ètíópíà, ní ọjọ́ àìkú, fún ìfilọ́lẹ̀ Prime Mínisità Abiy Ahmed fún ọdún márùn ún mìíràn ní ọ́fíísì.
Ọkọ ofurufuu aarẹ, Nigerian…