A kò fìgbà kan túra śilẹ̀ rárá – Ológun
Olùdarí ikọ̀ ogun HADIN KAI, ajagun Christopher Musa, ti fi dá àwọn ọmọ Nàìjíríà lójú pé àwọn aláṣẹ ológun kò fìgbà kan túra sílẹ̀.
Ajagun Musa fidi eyi mulẹ nitori, bi ọpọlọpọ awọn onijagidijagan ṣe tuba ni Ariwa…