Aṣojú Ethiopia kéde èròńgbà orílẹ̀-èdè láti darapọ̀ mọ́ NDB
Aṣojú Ethiopia si Brazil, Leulseged Tadese Abebe, ti sọ pé kí orílẹ̀-èdè òun jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ilé ìfowópamọ́ ìdàgbàsókè tuntun BRICS jẹ́ ọ̀kan lára ohun tó wà lọ́kàn òun fún ọdún tí a wà yìí.
Abebe ṣalaye ninu…