Aṣòfin tẹ́lẹ̀ rí gbóríyìn fún ìdájọ́ ilé-ejọ́ lórí ìdìbò gómìnà ní Zamfara
Ọmọ Aṣòfin Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ rí ti gbóríyìn fún ìdájọ́ ilé-ejọ́ lórí ìdìbò gómìnà tí ó gba Dauda Lawal, gẹ́gẹ́ bí gómìnà ìpínlẹ̀ Zamfara tí wọ́n dìbò yàn.
Bala Gamji ṣe igboriyin yii nigba ti o n fesi si…