Aṣòfin ìpínlẹ̀ Abia gbóríyìn fún ìdájọ́ ilé ẹjọ́ ìdìbò
Ọmọ ilé ìgbìmọ̀ Aṣojú tí ń ṣojú agbègbè Arochukwu/Ohafia ti ìpínlẹ̀ Abia, Ibe Osonwa (LP) ti kí Gómìnà Alex Otti ti Abia kú oríire lórí àṣeyege ní ilé ẹjọ́ ìdìbò.
Osonwa sọ pe idajọ naa fi ifẹ inu gbogbo eniyan …