Browsing Category
Ìròyìn Àyíká
Ìyàwó Ààrẹ Nàìjíríà Rọ Ọmọ Orílẹ-èdè Yìí Látì Tẹ́wọ́ Gba Ohun Àlùmọ́nì Agbára
Ìyàwó Ààrẹ Orílẹ-èdè yìí ti rọ àwọn ọmọ orílẹ-èdè yìí látì tẹwọ gba ohun alumọni agbara fún àyíká tó mọ́ tótó.
Ó sọ èyí nibi ọrọ rẹ láti sami sì ayeye ọjọ ayika to mọ́ toto agbaye ọdún 2026.
Arabinrin akọkọ rọ gbogbo ọmọ Naijiria…
Makinde Ṣèlérí Láti Ṣe Àfọ̀mọ́ Àṣà To Níí Ṣe Pẹ̀lú Àyíká Àti Àmójútó Ìdọ̀tí: Ó Búra Fún Aderinto…
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti ṣèlérí
pé ìṣèjọba rẹ̀ yóò dojú ìjà kọ àwọn àṣà eléyìí tí àwùjọ ti jinlẹ̀ nínú rẹ̀ lórí ayíká àti àmójútó ìdọ̀tí ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, fún ànfàní gbogbo ará ìlú.
Gómìnà ló sísọ lójú ọ̀rọ̀ yìí lásìkò tó n…
Ipinlẹ Anambra Gbé Ìgbésẹ Akínkanjú Nípa Títún Àyíká Àti Bèbè Omi Ṣe.
Ìjọba ìpínlẹ̀ Anambra pẹ̀lú àjọsọpọ̀ - "Initiative for Agulu Development" ní ọnà láti ṣe ìmọ́tótó sì àwọn agbègbè ti omi wà àti àwọn àyíká rẹ àti ni ọ̀nà láti jẹ́ kí ẹ̀gbin omi dínkù, wọn ti ṣètò ìmọ́tótó ní gbogbo bèbè omi àti ètò…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kwara Ri Asia Iṣọkan
Àárín gbùngbùn ipinlẹ Kwara ti ri ásíà iṣọkan oní àádọ̀rin Mítà ní gíga ti gómìnà AbdulRahman AbdulRazaq pé ìtúmọ̀ rẹ̀ ní "Iṣọkan àpapọ̀" - “national unity", àjọsọpọ Irinajo wà àti èròngbà wà gẹ́gẹ́ bí ènìyàn.
Ní ibi ìpàdé…
Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ti Jẹ̀jẹ́ Pé Àwọn Yóò Tún Ọ̀nà Benin-Sapele Se
Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti sèlérí pé àwọn yóò tún Ọ̀nà Benin-Sapele tó ti bajẹ tó wà ní ìpínlẹ̀ Edo, gúsù Nàìjíríà ṣe ní kíámọ́sá.
Mínísítà ipinlẹ fún iṣẹ ode, Bello Goronyo ló ṣe ileri yìí látàrí ẹ̀bẹ̀ láti ọdọ àjọ tl…
Mínísítà Múlele Lórí Ìwúlò Àjọṣepọ̀ Ilẹ̀ Òkéere Fún Ìtèsíwájú Ẹ̀ka Ètò Ìwakùsà
Ìgbákejì pataki nípa iroyin sì Mínísítà ìtèsíwájú àwọn ohun alumọni ilẹ̀,Segun Tomori ló gbé eleyi síta.
Dókítà Alake sọ pàtàkì ojuse ìwakùsà nípa ti ìlànà agbaye ní ti àjọ Organisation for Economic Cooperation and…
Orílẹ̀-èdè Nàmíbíà Ri Àrídájú Àjàkálẹ̀ Àìsàn Ẹṣin Adúláwọ̀
Ẹ̀ka tó wà fún ìtọjú àwọn ẹranko orílẹ̀-èdè Nàmíbíà ti kéde àjàkálẹ̀ àìsàn ẹṣín ilẹ̀ Adúláwọ̀ - "African horse sickness", wọ́n sì ti kófí àìsàn nàá lára márùndínlọ́gbọ̀n ènìyàn níbi ẹ̀ka ti ń mójú tó àwọn ẹranko ní agbègbè Otjinene,…
Ìjà Ìgboro Agbègbè Sọ Mẹ́ẹ̀dógún Ènìyàn Dolóògbé, Mẹ́rìndínlógún Farapa Ní Gúsù Sudan
Ó kéré tán ènìyàn mẹ́ẹ̀dógún ti dágbére f'áyé tí mérìndínlógún míràn sì tún farapa nínú àwọn ikọ̀lù ìjà Ìgboro agbègbè ní Tonj South County, Warrap State, Ariwa South Sudan, ẹnìkan sọ èyí ní ọjó Ẹtì.
Kọmísọ́nà Tonj South County, Ring Deng…
Ìdìbò Ọdún 2027: Ẹgbẹ́ Òṣèlú Labour Party Kòní Darapọ̀ Mọ́ Ẹgbẹ́ Mìíràn
Ẹgbẹ́ Òṣèlú Labour Party ti sọ pé àwọn koni darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ míràn ninu ìbò gbogbogbòò ọdún 2027.
Èyí jẹ ọkan lára kókó méjìlá àlàkalẹ̀ ìpinnu níbi Ìpàdé National Executive Council (NEC) ti wọn ṣe ní ọjó Ẹtì ní ìlú Abuja.
Nigba ti o ń…
Àjọ NUPEC Gbáradì Láti Dá Ààbò Bo Àwọn Ibi Ìwakùsà
Àjọ National Unity and Peace Corps, NUPEC sọ pé àwọn ti ṣetán ju àtẹ̀yìn wá lọ láti fi ààbò bo àwọn ibi Ìwakùsà káàkiri orílẹ̀-èdè yìí látàrí ìwé àbádòfin Ìfilọ́lẹ̀ tó de àjọ náà ti wọ́n yóò buwọ́lù.
Ọ̀gá àgbà patapata àjọ náà,…