Take a fresh look at your lifestyle.

Àlàkalẹ̀ Tí Ó Dúróore Ní Ọ̀pákùtẹ̀lẹ̀ Ìdàgbàsókè- Akọ̀wé Ìjọba Àpapọ̀

Akọ̀wé Ìjọba Àpapọ̀, Ọ̀mọ̀wé George Akume ti sọ pé àlàkalẹ̀ tí ó peregedé àti mímú iṣẹ́ dé ògóńgó ni yóò mú Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà dé ilẹ̀ ìlérí   Akume sọ ọ̀rọ̀ náà níbi àpérò àwọn alẹ́nulọ́rọ̀…

Àjọ NDE Se Àtìlẹyìn Ìdásílẹ̀ Iṣẹ́ Fún Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Ènìyàn Ní Ìlú Abuja

Àjọ NDE ti gbé ìgbésẹ̀ akin láti mú àdíkù bá àìrísẹ́ṣe àti láti lé òsì wọ̀gbẹ́ pẹ̀lú síṣe ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ènìyàn tí ó dín díẹ̀ ní ẹgbẹ̀rún mẹ́fà níbi tí wọ́n ti pèsè ohun èlò ìsiṣẹ́, èyí tí ó…
button