Ìdàgbàsókè Ìlú Àti Ìdájọ́ Òdodo Jẹ Ìjọba Lógún- Igbákejì Adarí Ilé Asòfin
Igbákejì Adarí Ilé Asòfin Keji, Ọ̀gbẹ́ni Benjamin Okezie kalu ti sàfihàn ìgbáradì ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti kẹ́gbẹ́ pẹ̀lú ojúgbà rẹ̀ l’àgbáyé nípa ìdàgbàsókè àti ìdájọ́ òdodo
Ó sísọ…