Take a fresh look at your lifestyle.

Ohun Ìwúrí Ní Ìjáwé Olúborí Lawal Jẹ́ Fún Ìpínlẹ̀ Zamfara- Kọmísọ́nà

Komísọ́nà Fún Ìfọ̀rọ̀léde Àti Àṣà ní Ìpínlẹ Zamfara, Alhaji Mannir Haidara ti sàpèjúwe ìdájọ ilé ẹjọ́ àpapọ̀ lórí ìdíje sí ipò gómìnà ìpínlẹ̀ Zamfara gẹ́gẹ́ bí èyí tí yóò mú ìdàgbàsókè bá ìjọba…

Ààrẹ Tinubu Kẹ́dùn Ikú Akọ́nimọ̀ọ́gbá Tẹ́lẹ̀rí Fún Ikọ̀ Agbábọ́ọ̀lù Super Eagles

Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu ti kẹ́dùn ikú Sebastian Brodericks-Imaseun tí ó jẹ́ akọ́nimọ̀ọ́gbá fún ikọ̀ àwọn okùnrin tí ó wà lábẹ́ ọdún mẹ́tàdínlógún, Ó sàpèjúwe akọ́nimọ̀ọ́gbá náà gẹ́gẹ́ bí ẹni málegbàgbé  …

Ìsẹ̀lẹ̀ Idagiri Ẹgbẹ̀rún Kan-lé-lẹ́ẹ̀dẹ́ẹ́gbẹ̀ta Ní Ó Wáyé Ní Ìpínlẹ̀ Eko Nínú Ọdún…

Àjọ tí ó ń mójútó ìsẹ̀lẹ̀ pàjáwìrì ní ìpínlẹ̀ Eko, (LASEMA) ti sọ pé, ó tó ìsẹ̀lẹ̀ ẹgbẹ̀rún kan lé lẹ́ẹ̀dẹ́ẹ́gbẹ̀ta tí ó wáyé láàrin ọjọ́ kíní osù kíní ọdún 2023 sí ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n osù kejìlá…
button